Home Posts tagged Mr Samuel Kojusola
Yoruba

Àwọn Òsìsẹ́ Fẹ̀yìntì Fi Àidùnú Hàn Lórí Ero Ìjóba Láti Yá Owó Ìfẹ̀yìntì Tí Wọ́n Dá Pamọ́

Ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ fẹ̀yìntí tí wọ́n ńlò ìlànà owó ìfẹ̀yìntì oní dídá, CPUN, ti fi àidùnú wọn hàn lórí ìpinu ìjọba àpapọ̀ àti ti ìpínlẹ̀ láti yá nínú àwọn owó ìfẹ̀yìntì tí wọ́n ńdá jọ. Gẹ́gẹ́bí àtẹ̀jáde látọ̀dọ̀ alága àjọ tó wà fún owó ìfẹ̀yìntì, Ọ̀gbẹ́ni Samuẹl Kojusọla se sọ, ìgbésẹ̀ yi yio Continue Reading