Home Posts tagged Mudashiru Ọbasa
Yoruba
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin nípinlẹ̀ Èkó ti lọ rí lára àwọn tí wọ́n fura pé, wọ́n fara kásá lásìkò ìfẹ̀húnúhàn Endsars láti lè mọ pàtó ètò ìrànwọ́n tí wọ́n yo se fún wọn. Igbákejì adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin, Ọ̀gbẹ́ni Wasiu Ẹshinlokun-Sanni, ló jẹ́ kọ́rọ̀ yí di mímọ̀, lásìkò ìjọko ilé ọlọ́jọ́ mẹ́ta pàtàkì láti mọ àwọn […]Read More...
Load More