Home Posts tagged Nnamdi Kanu
Judiciary

Court Refuses Kanu Bail

A Federal High Court in Abuja on Tuesday dismissed a fresh application for bail by the detained leader of the Indigenous People of Biafra, Nnamdi Kanu. The application was filed pending the determination of the treasonable felony charge against him by the Federal Government. Kanu, who is currently facing a seven-count charge, had in the […]Continue Reading
Yoruba

Ilé Ẹjọ́ Fi Asájú Ikọ̀ IPOB Síhamọ́ Di Ọjọ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n Osù Tónbọ̀

Ètò ìgbẹ́jọ asíwájú kan fún àwọn èyàn ilẹ̀ Biafra, IPOB, Nnamdi Kanu ẹni tọ́wọ́ àwọn agbófinro tún tẹ̀ lana, ni wọ́n yo tlsíwájú láti ma gbọ́ ìgbẹ́jọ́ rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrindinlọgbọn osù tón bọ̀. Nígbàtí ètò ìgbẹ́jọ́ bẹ̀rẹ̀, nílé ẹjọ́ gíga nílu Abuja, agbẹnusọ fún ìjọba Shuaibu Labaran bẹ̀bẹ̀ pé kí iléẹjọ́ tètè gbọ́ ẹjọ́ náà, […]Continue Reading