Home Posts tagged ògbéni Nnolim Nnaji
Yoruba

Ile Igbimo Asofin Agba Seleri Lati Mu Agbega Ba Papako Ofurufu Ilu Ibadan Kolee Ba Igbamu

Ìgbìmò tekoto Ile asòfin Àgbà fétò Ìrìnnà ojú òfurufú ti sèlérí pé, òun yóò mú àgbéga bá pápákò òfurufú ilè yìí to wà nílu ìbàdàn, lónà tí yóò fi ba ìgbàmu. Alága ìgbìmò tekoto Ile asòfin Àgbà fétò Ìrìnnà ojú òfurufú náà, sénítò Smart Adéyemí, ló sàlàyé èyí làkókò àbèwò won sí Gómìnà Sèyí Continue Reading