News Yoruba

Igbakeji aare ile yi, ojogbon Yemi Osinbajo ti sope ile yi ko ni pe so oro ipenija eto abo ton ba finra di afiseyin teegun alare fiso.

Igbakeji Aare soro yi lasiko ti egbe kan to n satileyin fun aare muhammadu Buhari sabewo si nilegbe aare L Abuja.
Gege bosewi, awon ipenija ton bale yi fira ni koni pe je rodo tile yi yoo si gbagbara otun pelu nini idagbasoke.
Ojogbon osinbajo wa ro awon lajo lajo, ati eleto abo nileyi lati mase kaare lori sise ise lori didaabo bo ile Nigeria.

Net / Olaopa

Yoruba

Igbakeji aare ile yi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti ro awon illse iroyin pe ki won parapo gbogun ti iroyin eke gbigbejade.

Ojogbon osinbajo  pepe yi nilu nilu Eko pelu alaye wi pe igbese bonkele ninu  eto akoso  ijoba ko dunkooko mo bo se ye ki ko maa o ri nile yi mo, bi ko se iroyin eke to gbode kan.

Igbakeji aare wa mu imoran wape ki awon ileese  iroyin fowo lile mu oro iroyin eke nipa bi won se je ileese to ye ko maa fonrere ododo.

Ojogbon Osinbajo salaye wi pe bi awon ileese iroyin se je eka kerin ninu eto ilu, o ye ki won maa la awujo loye lori ise digbadigba at sise deede.

Nigba ton salaye pataki awon ileese iroyin nile Nigeira nidi eto aseyori ijoba awarawa, igbakeji aare ro awon oniroyin pe ki won tunbo diro mo siso ododo nigba gbogbo.

Salaudeen

Yoruba

Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo sope pelu ipenija to nkoju ile yii, lati ogota odun toti gba ominira re, o se Pataki lati fojusun ojo-iwaju pelu ireti.

Ojogbon Osinbajo so eyi nibi eto idanileko Egbe NASFAT, fawon odo, pelu akori “Isokan, Alafia Ati Aseyori Ile Nigeria”.

Igbakeji Aare sodi mimo pea won odo ni ojuse toopo lati se nidi sisa mulo ati apinkari ohun alumoni.

Gege bi Ojogbon Osinbajo se so pe pupo iberu-bojo tawon eeyan ile yii nkoju ni rogbodiyan, aile to si ohun amayederun botiye , amo oni awon eeyan ile yi kogbodo kaare nidi ifesemule isokan ati idagbasoke ile yii.

Aminat Ajibike/Elizabeth Idogbe