Ijoba apapo ti fokan awon osise papako ofurufu ile yi bale lori aheso pe boya won yo da awon kan duro lenu ise nipa igbese tijoba fe gbe lori ati yonda awon oju opo oko ofurufu merin Pataki fawon ti yoo soo di otun. Alakoso eto irinna ofurufu nile yi Hadi Sirika lo fowo ero […]Continue Reading