Home Posts tagged Olómi ẹ̀rọ
News Yoruba

Àwọn ọmọ Ìsọta Ba ọkọ̀ Àjọ Olómi ẹ̀rọ Nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ Jẹ́

Akọ̀wé ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ẹ̀ka típínlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Muhammed Ibrahim, sọpé àwọn ọmọ ìsọọta ti báà ọkọ̀ tótóó mọ́kànlá tójẹ́ tàjọ olómi ẹ̀rọ nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ jẹ́. Ẹwẹ àwọn òsìsẹ́ àjọ ọ̀hún ti gùnlé ìyansẹ́lódì, tí wọ́n si se ìwọ́de lána òde yíì pẹ̀lú ìlérí títẹ̀síwájú nínú ìwọ́de náà lówurọ̀ òní. Continue Reading