Home Posts tagged Olóyè Owolabi Ọlakunlehin
Yoruba

Àwọn tówà nípò ìsàkóso ti pè fún ìfọwọ́sópọ̀ lórí fífòpin sí àisetò àbò.

Àwọn tówà nípò ìsàkóso, àwọn adarí ẹ̀sìn, àwọn ọmọ ìjọ Anglican, àwọn olùkọ́ ẹbí àti ọ̀rẹ́ ẹni tíìse Bisọbu ìjọ Anglican ẹkùn àríwá ìbàdàn, ẹni ọ̀wọ̀ ọ̀mọ̀wé Sẹgun Okubadejọ ni wọ́n péjú pésẹ̀ sínú gbọ̀gàn Banquet tówà nílé ìtura Premier ìbàdàn fún ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ ìwé ti ìránsẹ́ ọlọ́run náà kọ. Continue Reading