Home Posts tagged Omímọ̀ Nípa Ètò Ẹ̀kọ́
News Yoruba

Àwọn Omímọ̀ Nípa Ètò Ẹ̀kọ́ Fẹ́ẹ̀ Kíjọba Gbọn Wọ́ Sí Ẹnawo Ẹ̀ka Ètò Ẹ̀kọ́

Níbáyí tílẹ̀ Nàijírìa ń darapọ̀ mọ́ ilẹ́ àgbáyé tókù fún sísàmìn àyájọ́ ọjọ́ mọ́ọ̀kọ mọ́ọ̀kà lágbayé fún tọdún 2021 àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n kan lẹ́ka tón rísí ètò ẹ̀kọ́ àgbà, àti ẹkọ́ kíkọ́ọ̀ lailai, fk kí ìjọba gbọnwọ́ sí ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́. Wọ́n sọ̀rọ̀ náà nílu ìbàdàn lásìkò tí wọ́n ńsọ̀rọ̀ lórí pàtàkì Continue Reading