
Alaga igbimo to n risi akanse eto igbanise ijoba Apapo nipinle Oyo, Ogbeni Ope Salami ti so di mimo pe won ogba oro awon akanda eda roo lotun, ninu eto tgbigba awon osise egberun kan nijoba ibile kookan jake-jado ile yi. Ogbeni Salami so eyi lori eto ilese wa kan lede geesi, iyen “Straight-Talk” o […]Read More...