Yoruba

Ijoba Apapo Ti Gba Oro Awon Ti Won Ni Ipenija Ara Ro Fun Eto Igbanisise Akanse

Alaga igbimo to n risi akanse eto igbanise ijoba Apapo nipinle Oyo, Ogbeni Ope Salami ti so di mimo pe won ogba oro awon akanda eda roo lotun, ninu eto tgbigba awon osise egberun kan nijoba ibile kookan jake-jado ile yi.

Ogbeni Salami so eyi lori eto ilese wa kan lede geesi, iyen “Straight-Talk” o salaye pe, akanse eto ohun nireni waa pe yoo ware laarin osu kewa sosu kejila odun yi.

O salaye pe eniyoowu tobati ju odun mejidinlogun  lo le koopa ninu eto naa, o tokasi pe , formu yoo je pinpin, lawon ibudo igbanisise lawon ijoba inile metalelogbon nipinle Oyo, pelu alaye pe oro awon akanda eda yoo je gbigbaro.

Ogbeni Salami wa fida awon igbimo naa loju pee to ohun yoo ne gbangba lasa nta, pelu alaye pe won oni yan awon kan niposi.

O wa fikun pe igbimo naa yoo samulo gbogbo ona fi je kawon araalu mo bo senlo ti foomu naa ba ti jade.

Mosope Kehinde/Elizabeth Idogbe 

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *