Home Posts tagged Prof. Akin Abayomi
Yoruba

Alákoso fétò ìlera n’ípinlẹ̀ Èkó ní àrùn Covid-19

Alákoso fétò ìlera nípinlẹ̀ Èkó, ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Abayọmi ní àyẹ̀wò ti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pé ótiní àrùn covid-19. Alákoso fétò ìròyìn àti ọ̀rọ̀ àwùjọ nípinlẹ̀ Èkó Gbenga Ọmọtọshọ ló jẹ́ kọ́rọ̀ yí di mímọ̀ nínú àtẹ̀jáde kan tó fisíta lorọ òní. Àtẹ̀jáde náà tọ́kasi pé ọ̀jọ̀gbọ́n Abayọmi, ló mọ̀ pé òun Continue Reading