Politics

The chairman of the Independent National Electoral Commission, INEC, Professor Mahmoud Yakubu says there are no plans for electronic voting in the 2023 general elections.

Professor Yakubu announced this in Lagos in a speech at the National Broadcasting Commission, NBC, workshop on Broadcast Ecology and Politics in Nigeria.

The INEC Chairman attributed the development to the fact that the law on electronic voting has just been passed which left no time for the organization to test run the process.

Represented by Mr Segun Agbaje, Professor Yakubu gave the assurance that electronic voting would definitely be adopted for the 2027 elections.

Akinyinka Akintola

Yoruba

Ajo to n mojuto eto idibo nileyi, INEC ti sope ohun ti se eto gbogbo ti yoo maa safihan iyato to wa ninu awon ohun elo eto idibo to je ojulowo si awon to ba je ayederu.

Alaga ajo INEC, Ojogbon Mahmoud Yakubu soro naa nilu Akwa lasiko ipade awon torokan saaju eto idibo ti yoo waye nipinle Anambra.

Ojogbon Yakubu sope ajo ohun tun ti ri daju pea won oludibo ti ko ni ojulowo kaadi idiibo ni won o ni lanfani ati dibo lojo idibo.

O safikun oro re pea won ohun elo idibo ti ko se koko lawon ti ko lo, sawon ijoba ibile mokalegun ipinle naa.

Ni bayi naa, oga abga yanyan ile ise olopa ile yi, Usman Alkali Baba ti jeko di mimo pe apapo olopa bi egberun merinlelogbon ati orinleleedegbeta ati meje ni yoo maa sise po pelu awon eso alaabo min fun fifese eto abo rinle nibi eto idibo ti yoo waye lojo abameta naa.

O wa ro awon araalu lati mase foya lori kiko ogunlogo eso alaabo jade feto idibo naa, pelu ileri pe won yoo ri daju pea won sise won pelu jije akosemose bee lotun ro awon to n gba lero lati da wahala sile lati kowo omo won boa so.

Merin ninu oludije mejidinlogun fun ipo gomina lo yoju sibi ipade naa.

Folakemi Wojuade