Ègbé olùkọ́ láwọn ilé ẹ̀kọ́ Fáṣítì nileyi, ASUU tí sewele iyanselòdi olosu mejo rẹ pẹ̀lú àwọn afẹnukò ìlànà kan. Alága ẹgbẹ́ náà fún olú ìlú wa Abuja, Ojogbon Kasimio Umar ló fìdí ọ̀rọ̀ náà múlè fáwọn akoroyin nilu Abuja. Ègbé náà pinnu láti fòpin sí iyanselòdi ohun lásìkò ìpàdé àwọn Continue Reading