Ogunlọ́gọ̀ àwọn obìnrin ni wọ́n yan bí ológun lọ sílé ìjọba nílu Port-Harcourt láti lọ fi ẹ̀húnú hàn lórí ìsekupa àwọn ọ̀dọ́bìnrin ní àwọn ilé ìtura ọ̀tọ̀tọ̀ n’ípinlẹ̀ Rivers. Àwọn obìnrin shún ni wọ́n wọ asọ dúdú, tí wọ́n sìn késí ìjọba láti gbé ìgbésẹ̀ burúkú náà. Wọ́n tọ́kasi wípé Continue Reading