Yoruba

Àwọn obìnrin fẹ̀húnú hàn lórí ìsekúpani nílé ìtura

Ogunlọ́gọ̀ àwọn obìnrin ni wọ́n yan bí ológun lọ sílé ìjọba nílu Port-Harcourt láti lọ fi ẹ̀húnú hàn lórí ìsekupa àwọn ọ̀dọ́bìnrin ní àwọn ilé ìtura ọ̀tọ̀tọ̀ n’ípinlẹ̀ Rivers.

Àwọn obìnrin shún ni wọ́n wọ asọ dúdú, tí wọ́n sìn késí ìjọba láti gbé ìgbésẹ̀ burúkú náà.

Wọ́n tọ́kasi wípé gbogbo èyàn pátápátá lái yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀, tófimọ́ ẹni tón sòwò nààbì lóní ẹ̀tọ́ sí ìgbéayé tí kòsì yẹ kí wọ́n jẹ́ pípa ní pa kúpa.

Ìròyìn ti sọ di mímọ̀ pe kòdín ní ọ̀dọ́ bìnrin mẹ́jọ tí wan ti salábapàdé ikú òjijì nílé ìtura ọ̀tọ̀tọ̀ nípinlẹ̀ Rivers, larin osù méjì tó kọjá.

Kemi Ogunkọla/Sheriff Nasirudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *