Home Posts tagged Workers' Vaccination
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Sèkìlọ̀ Fáwọn Òsìsẹ́ Lórí Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19

Sáàjú gbèdéke ọjọ́ kini osù kejìlá, fún gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn Covid-19 fáwọn òsìsẹ́ ìjọba, ìjọba àpapọ̀ ti sèkìlọ̀ fáwọn òsìsẹ́ tó fẹran isẹ́ wọn láti lọ gba abẹ́rẹ́ àjẹsára. Pẹ̀lú onírunru ẹrọ tón tẹlẹ ọ̀rọ̀ yíì, èyító jẹ́ kíkéde lósù kẹsan, ìjọba ni ìgbésẹ̀ náà wáàyé níbamu pẹ̀lú ifẹ̀ Continue Reading