Home Posts tagged Youth unemployment
Yoruba

Olósèlú kan ńfẹ́ kí òfin wà lórí ipèsè isẹ́ fáwọn ọ̀dọ́

Ó yẹ kí ilé ìgbìmọ̀ asòfin gbé òfin ìjọba ìpínlẹ̀ láti pèsè isẹ́ fún ọ̀dọ́ tó bá ti pé ọdún mọ̀kànlélógún. Ọrọ yí ló tẹnu, olósèlú títún se olùdarí kan, ọ̀mọ̀wé Fọla Akinọsun jáde lásìkò tón kópa lórí ètò kan Premier F.M, tí wọ́n pè ní “The Stage”. Ọmọwe Akiọsun sọ pé ìjọba ní láti […]Continue Reading