Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà nílẹ̀ Nàijírìa, NGF, sọpé àwọn ńse àtòpọ̀ àkọlé ètò ìsúnná wọn lọ́wọ́, káwọn tó lèè mọ̀ báwọn yóò se ìdápadà owó ìyọnilọ́fìn tíjọba àpapọ̀ fún wọn.

Alága ìgbìmọ̀ ọ̀hún títún se Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì, ọ̀mswé Kayọde Fayẹmi, ẹnitó sọ̀rs yíì lkyìn ìpàdé alátìlẹ̀kùn mọ́rí se kan nílu Abuja.

Ó sàlàyé pé, àwọn Gómìnà gbàgbọ́ pé báwọn se ti setán láti san owó, àwọn gbọdọ̀ se àtòpọ̀ àkọlé ètò ìsúnná wọn.

Gómìnà Fayẹmi ẹnitó sàpèjúwe ìgbésẹ̀ báwọn òsìsẹ́ elétò àbò se yabo ilégbe àwọn Gómìnà lẹ́nu lọ́lọ́yii gẹ́gk bí èyítí kòbófin mu, sọpé ìgbìmọ̀ náà ti sèpàdé pọ̀ pẹ̀lú ààrẹ àti ọ̀gá àgbà ilésẹ́ ọlọ́pa ilẹ̀ yíì lórí ọ̀rọ̀ ọ̀hún.

Kẹmi Ogunkọla/Oluwakayọde Banjọ

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *