Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó fi ìrètí hàn láti pinwọ́ ìarísẹ́se

Gómìnà ìpínẹ̀ Òndó, ọ̀gbẹ́ni Rotimi Akeredolu ti sọ́ di mímọ̀ pe ètò ìsèjọba òhun yóò fojúsùn ètò ọ̀gbìn gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan gbogi láti wójùtú sí àinísẹ́ lọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ nípinlẹ̀ náà.

Gómìnà Akeredolu sọ èyí níbi ìfilalẹ̀ ìwé kan nípinlẹ̀ Èkó.

Ó sàlàyé pé, àinísẹ́ lọ́wọ́ jẹ́ ìpèníjà kan gbogi tó ńkojú àwọn ọ̀dọ́ tósìrọ ìjọba nígbogbo ẹ̀ka láti pèsè isẹ́ fáwọn ọ̀dọ́ káakiri ilẹ̀ Nàijírìa.

Kẹmi Ogunkọla/Amos Ogunrinde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *