Yoruba

Ile Asofin gbe igbimo iwadi kale lori Epo robi

Ile Igbimo asofin keji ti fenu ko lori sise iwadi fini-fini lori epo robi tawon kan nji lododun eyi towore too Trillionu marun Naira.

Eyi lo tele aba ti Ogbeni Chuuwuma Umeoji gbe siwaju ile nibi ijoko ile ti igbakeji Adari ile , Ogebeni Ahmed Wase dari re.

Ewe ile ti wa gbe igbimo eleni metala kale eyiti igbakeji omo egbe topoju nile igbimo asofin ohun, ogbeni Peter Akpatason lewaju, pelu erongba lati sewadi iye epo robi ti ile yii npese lojumo.

Igbimo ohun niwon pase pe ogbodo sise to iwadi iye epo ti ile yii pese, ohun tita lojojumo loja agbaye ati nile Nigeria lapapo.

Ogunkola/Toba

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *