Yoruba

Ijoba Apapo bomi suuru mu fawon osise lori owo osu tuntun

Ijoba Apapo orilede yii ti loun yoo tun Sagbekale awon igbimo tuntun lati bere idunadura lakotun fun sisamulo owo sosu tuntun awon osise to kere julo.

Alakoso foro ise ati igbanisise, omowe Chris Ngige lo siso loju oro yii, lakoko tawon olori Egbe osise wa sabewo si nilu Abuja.

Osalaye pe, o se Pataki fawon osise to n gbaju Egberunlona Ogbon naira lo losu atawon to wa lakaso ipele ise keje si metadinlogun lo se suuru, nitori won n woju tu si sisamu lo re yoo si yaa Kankan.

Aare Egbe NLC, Ogebeni Ayuba Wabba, Salaye pe, Ojuse  egbe naa ni lati dabobo eto awon osise re, pelu afikun Egbe NLC ti keko latara awon igbese re ateyin, wa ton si ti setan lati ridaju pe, Alafia ati isokan joba laarin awon osise.

Ogunkola/Toba

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *