Yoruba

Ilé isẹ́ ọmọ ológun òfurufú bẹ̀rẹ̀ ìdánilẹ́kọ lórí ìrólágbára ètò àbò abẹ́lé

Ilésẹ́ ọmọ ológun ojú òfurufú, ti bẹ̀rẹ̀ ìdánilẹ́kọ fáwọn òsìsẹ́ pàtàkì rẹ̀ láti mágbaga bá ètò àbò ilẹ̀ yíì.

Olùdarí ẹ̀ka ìròyòn nílesẹ́ náà, ọ̀gágun Ibikunle Daramọla sọ èyí di mímọ̀ nínú àtẹ̀jáde kan nílu Abuja.

Ọgagun Daramọla sàlàyé pé, ìdánilẹ́kọ ọ̀hún tó jẹ́ ẹlẹ́keje irú rẹ̀ nílesẹ́ ọ̀hún, lójẹ́ ìdánilẹ́kọ àkọ́kọ́ nípinlẹ̀ Bauchi.

Ó fikun pé, wọ́n yan ìpínlẹ̀ Bauchi, kí àgbéga lèèbá isẹ́ àwọn òsìsẹ́ ilésẹ́ náà nípinlẹ̀ Bauchi, kádinkù tún lè bá ibùdó ìdánilẹ́kọ nípinlẹ̀ Kaduna.

Oluwayẹmisi Dada/Kẹmi Ogunkọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *