Yoruba

Egbe Osise Pe Fun Sisan Ajeele Ekunwo Owo Osu Titun

Egbe awon Osise TUC, ti kesi ijoba apapo lati san ajele ose marun owo-osu titun lati ojo kejidinlogun osu kerin odun 2019, lakoko ti Aare Muhammadu Buhari fowosi owo osu titun naa.

Ijoba ati awon egbe osise fenu oro koo lori owo osu titun ohun lojo eti tokoja, leyin ojo okoodinigbalemeji t’Aare Muhamadu Buhari fowo saba naa.

Ninu atejade kan, tegbe awon osise ohun ti ro ijoba lati mu ileri re gbogbo lori owo osu titun naa se.

Nigba to ndupe lowo awon adari egbe osise, atawon torokan, ni egbe awon osise naa so fawon olugbanisise wipe ilese yoowu toba san owo todin si owo osu titun naa yo je fifiya je.

Oluwayemisi Dada\Kemi Ogunkola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *