Security

Ijoba apapo gbe igbese lati dekun igbesunmomi

Ijoba apapo ti seleri lati raa awon nkan ijagun tofimo awon oko oju ofurufu tiwon nlo fun ijagun lati ile Russia nidi gbigbogunti igbesimomi ati iwa odaran nile yi.

Olubadamoran pataki saare foro iroyin ati ibaraalusoro, Malam Garba Shehu lo so eyi di mimo ninu atejade kan.

Olubadamoran pataki ohun to k’owo rin pelu aare losi ile Russia sope awon adari ile yi yoo so asoyepo lori eto abo pelu aare ile Russia, Vladimir Putin nibi ipade apero ile Russia ati orileede Nigeria.

Gege bi Malam Shehu se wi, awon orileede mejeji yoo fenu oro ko lori ona lati seranlowo fun ile Nigeria lona ati fopinsi iwa igbesunmomi lawon apa ibikan lorileede yi.

Oluwayemisi Dada/Kemi Ogunkola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *