Yoruba

Gomina Makinde S’atunto Eka Eto Ilera

Gomina ipinle Oyo, onimo ero Seyi­­­ Makinde sope eto isejoba toun lewaju yoo ko awon eka kan kuro n’ile iwosan Jericho losi ibudo ti won ti ntoju ipenija oplolo nile iwosan naa.

O so eyi di mimo nigba to nba awon oniroyin soro leyin to s’abewo si ibudoko atijo, sanyo ni ile-iwosan Jericho ati ibudo itoju ipenija opolo Jericho Ibadan.

Gomina Makinde enito sope igbese kiko awon eka naa lati ibikan si ibomiran yoo bere k’odunyi to pari.

Bakana lo pase pe k’alaga ajo to n samojuto sunkere fakare oko nipinle Oyo OYRTMA lati so ibudoko atijo naa di olu-ilu ajo ohun to si seleri lati fi awon ohun amayederun atawon irinse toye sibe lati mu ayika naa dara dunmo fun ise.

Oluwayemisi Dada\Kemi Ogunkola

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *