Yoruba

Ajo NAFDAC pe fun ijiya to gbopon fawon to nko ayederu oogun wolu

Ajo to nrisi ipeniye ounje atoogun nile yii, NAFDAC, ti pefun ijiya to gbopon feniyoowo tabi ajo to ba nko ayederu ogun tabi se fayawo oogun wo orileede yi.

Oludari agba ajo naa, Ojogbon Mojisola Adeyeye so eyi nilu Abuja.

Ojogbon Adeyeye wa bu enu ate lu ijiya ti ko gbopon too wan le fawon to nse fayawo oogun tramadol atawon oogun ayederu mii, to sir o eka eto idajo lati satungbeyewo ofin ati ijiya to ro mo.

Oga agba ajo NAFDAC ohun, wa gboriyin fun ijoba apapo f’atileyin re f’ajo naa.

Oluwayemisi Dada/Kemi Ogunkola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *