Yoruba

UNICEF n gbèrò abere ajesara tí yó dènà àìsàn ibà ponju ponto ni ìpínlè Èkìtì

Ẹ̀ka àjọ kan lorileèdè àgbáyé tó ń rísí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọdé, UNICEF, n gbèrò láti fún àwọn èèyàn bí milionu méjì ni abere ajesara tí yó dènà àìsàn ibà ponju ponto ni ìpínlè Èkìtì.

Aṣojú àjọ eleto ìlera lagbaye to ń sise ńipinle Èkìtì, Ogbeni Ayomide Aibinuomo sọ pé, àìsàn ibà pọ̀nju ponto leè mú ẹ̀mí èèyàn lọ, nítorípé ó ti pàá ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lápá àríwá orílèèdè yi, ṣùgbọ́n àìsàn òun kò fibe wọ́pọ̀ ní apá gúsù.

Ogbeni Aibinuomo sọ pé ètò abèrè ajé sára tó ń dènà àìsàn ibà pọ̀nju ponto na, yo sì wà fún gbígbà títí di ìparí oṣù yìí. 

Ogunkola/Ladele

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *