Idaduro bá ètò kálọ kabo ọkọ ní ojú pópóná lágbègbè molète nílù Ìbàdàn láro òní, nígbàtí àwọn awako ọkọ̀ kèké elesemeta tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ sì kèké marwa ṣe ìwọde tako òfin tuntun tí ìjọba see, pé wọ́n ko gbọdọ gbé èrò síwájú tí yo jóko lègbe direba.

Àwọn awako kèké elese mẹ́ta nà, dúró sáàárín ọ̀nà tí wọ́n sì ń dáà àwọn elegbe wọn tó fi ọkọ̀ gbero dúró, pé kí wọ́n já èrò tí wọ́n gbé sílè, torí pé àwọn kò ní sise lóni. 

Lára àwọn tó ń fehunu hàn na, ṣàlàyé fún oniriyin wa pé, kò lè seese káwọn má gbe eèrò síwájú, tí yó jóko lègbe direba toripe owó goboi láwọn ń san sapo ìjọba ńipinle, ìjọba ìbílẹ̀, kooda àwọn Ọlọpa na ngbà nínú owó táwọn bá pàá.

Ogunkola/ibomor

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *