Yoruba

Ajo Eleto Ilera, WHO, Samulo Ijo Esin Lati dena Itankale Arun Coronavirus

Ajo eleto ilera agbaye, WHO, ti gbe ipolongo lori a ti dena arun Korona laarin awon omo ileyi, gba odo awon olori esin lo ni ipinle Ogun.

Ilaniloye lori ati dena arun naa ni won se fun awon Lemomu ati Alufa ninu Mosalasi Ilu Egba, to wa ni Kobiti, nilu Abeokuta.

Akoroyin wa j’abo iroyin wipe awon akopa ninu ipolongo ilaniloye naa ni won kojopo lati awon Mosalasi  ati legbelegbe ijo Musulumi kaakiri ijoba ibile to wa nipinle Ogun.

Wale Oluokun

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *