Lifestyle

Àjọ tí kíìse tìjọba pè fún ìtójú tó péye fún àwọn arúgbó

Wọ́n ti rọ ìjọba pé kí wọ́n kó ipa tó jọjú nídi sisẹ́ ìtọ́jú àwọn arúgbó láwùjọ.

Àarẹ ibùdó kan tó ń jẹ́ Omishina Homes, nílu ìbàdàn.

Oloye Adio Modupẹọla ló pèpè yí lásìkò tó ń sọ̀rọ̀ nípa àyájọ́ olidena ìfìyajẹ arúgbó èyí tí akọ̀rí rẹ̀ dá lórí ipa àjàkálẹ̀ àrùn covid 19 lórí àsìlò àti pápa àwọn arúgbó tì.

Olóyè arábìnrin Modupẹọla tẹnomọ pé, kò yẹ kí wọ́n pa àwọn arúgbó tí àti pé ó se pàtàkì fúnjọba larí náà kún àwọn àjọ tí kíì se tìjọba lọ́wọ́ nídi ìtọ́jú àwọn arúgbó.

Oloye Mdupẹọla tún rọ àwọn èèyàn tó bá ní arúgbó lọ́dọ̀ pé kí wọ́n ma tọ́jú òbí wọn dáàdáà.

Ìyá àgbà Modupẹọla késíjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ pé kí wọ́n túnbọ̀ gbájúmọ́ ìtọ́jú arúgbó.

Oluwayẹmisi Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *