Alaga egbe awon Musulumi nipinle Oyo, Alhaji Kunle Sanni sope oun ofaramo igbese sisi awon ibudo ijosin nipinle Oyo.

Alhaji Sanni, nigba to nba awon oniroyin soro nilu Ibadan sope loto egbe awon Musulumi nipinle Oyo koti gbe igbese yoowu lori ipinu ijoba lati sii awon ile ijosin, amoo ohun ko faramo igbese naa nitori bi aleekun se ti n baa akosile arun Covid-19.

Alhaji Sanni sope esin Islam faye gba awon olujosin lati gbadura nile kowa nigba yoowu tajakale arun bawa.

Ewe, adari awon Musulumi oun wa fikun pe igbese tin lo lowo lati sepade po pelu awon Musulumi nibiti kowa yoo ti so ero re lori igbese naa.

Yemisi Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *