-
Egbe Awon Musulumi Nipinle Oyo Tako Sisi Awon Mosalasi Pada
Alaga egbe awon Musulumi nipinle Oyo, Alhaji Kunle Sanni sope oun ofaramo igbese sisi awon ibudo ijosin nipinle Oyo. Alhaji Sanni, nigba to nba awon oniroyin soro nilu Ibadan sope loto egbe awon Musulumi nipinle Oyo koti gbe igbese yoowu lori ipinu ijoba lati sii awon ile ijosin, amoo ohun ko faramo igbese naa nitori…