Yoruba

Ijoba Apapo Setan Lati Gbe Opopona Nla Fawon Olokowo Aladani

Ijoba apapo ti setan lati fa opopo naa nla mewa lorile ede yii fawon olokowo aladani.

Alakoso fawon ise-ode, Babatunde Fashola, lo so eyi lasiko to fi abo igbese naa je fawon igbimo tekotoo ile asofin ofin foro ise odo.

Alakoso Fashola so di mimo pe awon olokowo adani naa ni yoo seto amojuto ati atunse awon ojuna ouun. O sope igbese naa yoo madinku baa owona ijoba tiyoo si pese ise tootoo egberun merinlelogun.

Alakoso fikun pe awon ona ouun nii: Benin-Asaba, Abuja-Lokoja, Kaduna-Kano, Onitsha-Owerr-Aba, Shagamu-Benin, Abuja-Keffi-Akwanga, Kano-Maiduguri, Lokoja-Benin, Enugu-Porth-Harcourt, Ilorin-Jebba.

Yemisi Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *