Awon adari esin to kesi ijoba apapo lati wa ona topin yoo ri ba, igbese bawon darandaran atawon jaguda se nlo ohun ija-oloro fi koolu awon alaise.

Sultan Sokoto Alhaji Muhammadu Sa’ad, Abubaka keta ati Aare egbe awon omoleyin Kristi, CAN, Eniowo Samson Ayokunle tiwon dijo lewaju igbimo to nrisi oro esin NIREC bere fun eyi, nitori iwa ipani nipa kupa atawon ipenija eto abo minn to nkoju ile yii.

Nine atejade kan, ti akowe ajo NIREC Ojogbon Cornelius Omonokhua, fowosi sope awon adari esin mejeeji koroo- oju si iwa ipa lori awon omoniyan paapaa isekupani towaye lenu looyi, ni Sokoto, Zamfara, Kogi tofimo ikolu awon eso alabo gomina ile Borno Babagana Umara Zulum.

Awon adari esin ohun, wa kesi ijoba lati pese aboo to gbopon fawon eeyan ile-Nigeria.

Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *