Ajo to nrisi ikaniyan nileyii, NPC, ti kede pe, awon iwe eri ibi, eyi tawon ijoba ibile ati ile-iwosan ngbekale, kole je sisamulo fun awon ojuse kan nile yii.

Ajo naa tokasi pe, ojuse ajo NPC ni fifun ni ni iwe eri ibi je nibamu pelu ofin ile yii todun 1999.

Adele alaga ajo NPC, Omowe Eyitayo Adetunji so eyi fun oniroyin Radio Nigeria n’ilu Abuja.

Omowe Adetunji ro ijoba atawon osise eleto ilera lati seto ilaniloye fawon obi lati seto iforuko sile awon omo won.

Nigba to un fesi, osise agba ajo UNICEF, Enugu, Ogbeni Ibrahim Conteh salaye pe, akosile lenu loloyi, safihan re pe iforuko sile awon omo wewe nile yii kere jojo pelu bi ida metadinlogota awon omo kise je fiforukosile nikoko.

Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *