
Ajo to nrisi ikaniyan nileyii, NPC, ti kede pe, awon iwe eri ibi, eyi tawon ijoba ibile ati ile-iwosan ngbekale, kole je sisamulo fun awon ojuse kan nile yii. Ajo naa tokasi pe, ojuse ajo NPC ni fifun ni ni iwe eri ibi je nibamu pelu ofin ile yii todun 1999. Adele alaga ajo NPC, […]Read More...