Àjọ tó ńrísí ìtànkálọ̀ áàrùn nílẹ̀ yíì, NCDC, ti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn orílẹ̀èdè Nìajírìa láti sọ́ráà fáwọn ọ̀bàyé-jẹ́ tí wọ́n ńpè rawọn lósìsẹ́ àjọ NCDC, fi lu àwọn èèyàn níjìbìtì.

Àjọ náà fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pe, òhun ó sètò fífún ẹnikẹ́ni láti lọ́wọ́, bẹni ohun ó bẹ̀rẹ̀ owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni láti gbàwọ́n sísẹ́.

Olórí ẹ̀ka ìwádi làjọ NCDC, arábìnrin Elsie, Kori sọ̀rọ̀ ìkìlọ̀ yíì lána nígbà tájọ náà ń fàbọ̀ rẹ̀ jẹ́.

Ó sàlàyé, pé, isẹ́- ìwádi ti ńlọ lọ́wọ́ lórí ọ̀rọ̀ náà tósì sèlérí pé, ẹnikkni táàje ìwà-ìbàjẹ́ ọ̀hún básímọ́ lóòrí yóò fimú káàta òfin.

Arábìrin Ilọri, wá sàlàyé pé èsì àyẹ̀wò àrùn covid-19, ti kótèètèè majade tí ńjẹ́ wíwójú tusi, pẹ̀lú ìgbésẹ̀ tóòyẹ pẹ̀lú ìjọba ìpínlẹ̀ kọ̀kan èyí tí yóò mu késì àyẹ̀wò máà jáde lójú-ọjọ́.

Ẹwẹ, Arábìrin Ilọri, wá bẹnu áàtẹ́lu ìwà báwọn èèyàn orílẹ̀èdè yíì kan, kíì se sọ óòtọ́ọ̀ nípa-arawọn èyí tó ńmú níráà fájọ náà láti fún wọn léèsì àyẹ̀wò wọn, tóbá jáde, tósì fikun pé orílẹ̀dè Nìajírìa tini ibùdó àyẹ̀wò ( Laboratory) mẹ́rìnlélọ́gọ́ta yàtọ̀ọ̀ síì márun tóòní lósù kẹta ọdún yíì.

Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *