Home Posts tagged NCDC
Yoruba
Káabo tó péye le wà láwọn ibùdó ìfinimọ́lé fáwọn àgùnbánirọ̀ yíká orílẹ̀èdè yí, àjọ tón gbógunti ìtànkẹ́lẹ̀ àrùn ti sọpé gbogbo àwọn tó fẹ́ sìnrúlu ni wọ́n yo se àyẹ̀wò fun nípa irinsẹ́ tuntun fún síse àyẹ̀wò fún àrùn COVID-19. Olùdarí àjọ náà Ọ̀mọ̀wé Chukwe Ihekweazu ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón jíròrò papọ̀ pẹ̀lú àwọn […]Continue Reading
Yoruba
Àjọ tó ńrísí ìtànkálọ̀ áàrùn nílẹ̀ yíì, NCDC, ti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn orílẹ̀èdè Nìajírìa láti sọ́ráà fáwọn ọ̀bàyé-jẹ́ tí wọ́n ńpè rawọn lósìsẹ́ àjọ NCDC, fi lu àwọn èèyàn níjìbìtì. Àjọ náà fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pe, òhun ó sètò fífún ẹnikẹ́ni láti lọ́wọ́, bẹni ohun ó bẹ̀rẹ̀ owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni láti gbàwọ́n sísẹ́. Olórí ẹ̀ka […]Continue Reading
Health
Since the outbreak of Covid-19 pandemic, World Health Organisation, W.H.O, recommended the use of face mask or shield to curb the spread of the disease. Also, the Presidential Task Force on Covid-19, on April 27th mandated the use of face masks or covering in public places in view of the ways in which the virus […]Continue Reading
Load More