Olórí àwọn ọmọ ológun orílẹ́ẹ̀ ọ̀gágun Gabriel Ọlanisakin, tu fọwọ́ ìgbáradì ilésẹ́ náà sọ̀yà láti sàtìlẹyìn fún ìfẹsẹ̀múlẹ̀ àlafìa jákè jádò àgbáàyé.

Ọgagun Ọlonisakin, sọ èyí nílu Abuja, níbi ìfilọ́lẹ̀ ikọ̀ àtìlẹ́yìn àláfìa, PSOS, ibùdó tó ńrísí ìmọ̀ ìwádi CSRS àti ilé-ẹ̀kọ́ tó ńrísí ọ̀rọ̀ àbò, NDC.

Nígbà tó ńsojú, olàdarí ikọ̀ àlàfìa lólú-ìlú, ilésẹ́ ètò àbò, ọ̀gágun àgbà, Henry Ayamasaowei, ọ̀gágun Olonisakin wá fi ìdùnú rẹ̀ hàn lórí bíì ìjọba ilẹ̀ Japan se tukọ̀ isẹ́ àkànse ọ̀hún, nípasẹ̀ ètò ìdàgbàsókè àjọ ìsọ̀kan àgbáàyé (UNDP) pẹ̀lú àtọ́kasí pé irúfẹ́ ìbásepọ̀ bẹ́ẹ̀ yóò mú àgbéga ilẹ̀ Níajírìa, rúgọ́gọ́ síì tó sì rọ àjọ NDC, láti máse fàyègba, kí ìbásepọ̀ yíì yamọ bótiwù ọ́mọ.

Ilé-ẹ̀kọ́ ètò àbò, NDC, Rear Admiral Mackson Kadiri, sọpé ètò ọ̀hún wáyé láti fẹsẹ̀ àbò múlẹ̀ lábẹ́ àjọ, Ecowas, lajọ ìsọ̀kan ilẹ̀ Africa, àjọ ìsọ̀kan àgbáyé nídi àfojúsùn àláfìa.

Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *