Ilese Ologun nile yi ti loun nfe ifowosowopo Ijoba Ipinle Ogun nidi fifi ese abo mule dain-dain nipinle naa.

Oga Agba to n sakoso, ile ise Omo Ologun Owo Kokalelogorun nilese omo Ologun, Ogagun Agba Godwin Umelo enito soro yi nilu Abeokuta lasiko to sabewo sii Gomina Dapo Abiodun sope ohun wasi ipinle naa fun abewo too ye labe ekun naa.

Ogagun Agba Umelo enito salaye pe, gbogbo igbese gbodo je gbigbe gbodo je gbigbe lati fese abo to loorin mule.

Nigba to nfesi, Gomina ipinle Ogun, Omo-oba Dapo Abiodun, gboriyin fun awon osise ilese omo-ologun fun sisa ipa nidi didabobo orileede yii ohun sise atileyin fawon ajo eleto abo min, lati fese Alafia muile nipinle.

Gomina Abiodun wa seleri lati tubo,gunle eto ilaniloye araalu ati sise kariya ipinle ogun, latiri anfani to wa ninu ise ologun.

Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *