Ile-Ise Radio Apapo Ile Wa, FRCN, Beere Fun Titu Bo Nawo Goboi, Silese Naa Fun Ijafafa Re


Ile-ise Radio Apapo ile wa, FRCN, ti beere fun titunbo nawo to joni sile se ohun, ko le ba maa sise re gege bi ise, nibamu pelu ife Araalu.

Oludari Agba patapata funleese Radio Nigieria, Omowe Mansur Liman lo parowa yi nibi ipade ita gbangba kan to waye nilu Abuja, lakoko to n dahun awon ibere lolokan o jokan latodo agbarijopo igbimo tekoto ile Asofin Agba lori owo isuna ataabo gbogbo, tofimo tigbaradi fagbekale liana, owona f’odun 2021 s’odun 2023.

Omowe Liman so fun igbimo tekoto ile Asofin Agba ohun pe ile-ise naa nilo owo goboi lati paaro awon irinse tojo tilo lori won nilese ohun, pelu alaye igbese bawon ajo ijoba kan-kan se sanwo ise tiwon se, lori afefe, ko sanfani Kankan fun ile-ise ohun.

Alaga Igbimo tekoto ile Asofin Agba feto isuna, Senator Solomon Olamilekan wa gba ile ise FRCN niyanju lati gunle awon liana eyi tiwon file tunbo maa rowo pawole labele.

Eto ipade itagbangba naa lo wayelati fi wojutu si aba eto isuna ile yee lai fise ipalara fenikankan.

Folakemi Wojuade


Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *