Ijoba ipinle Osun sope oun yoo samulo nkan alumoni inu-ile,eto ogbin,ati eka irinajo afe fi mu amugbooro ba eto oro aje ipinle ohun.

Gomina ipinle osun ,ogbeni gboyega oyetola so eyi nibi eto idanileko kan, eyi ti ijoba ibile naa sagbekale re lati saamin odun mokandinlogboan ti ipinle osun je dida sile.

Gomina Oyetola enito salaye pe ohun nsise fifese eto oro-aje ipinle naa mule dada, tokasi pe ijoba re yoo tesiwaju nidi mimu agbega ba igbe aye Alafia araalu tofimo fifese aabo mule gboin-gboin.

Temitope Mosadomi / Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *