Yoruba

Eeyan merin j’olorun nipe nibi isele ijamba oko baalu nilu eko

Awon eeyan merin lo ti j’olorun nipe nibi isele ijamba oko baalu kan tamosi, helicopter to jalule ni agbegbe Salvation Bus-Stop ni Opebi to wa nilu eko, ni dede ago mejila osan.

Agbenuso fun Ajo to n risi isele pajawiri nipinle eko, ogbeni Nosa Okunbor lo fidi isele naa mule fawon oniroyin.

 Ko sai fikun pe, won ti gbe awon eeyan min to farapa nibi isele naa lo sile iwosan fun itoju.

Folakemi Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *