Ile ise ijoba apapo to n ri soro igbokegbodo oko ti gunle eto didekun awon ibudo ti o bofin mu, ohun fifopin si iwa ajebanu lawon oju ona to lo sibudoko oju omi nilu Eko. Akowe agba nile ise ohun, Arabinrin Magdalene Ajani to salaye pe ko din ni ibudo ayewo merindinlogbon ni ko ba […]Continue Reading
Awon eeyan merin lo ti j’olorun nipe nibi isele ijamba oko baalu kan tamosi, helicopter to jalule ni agbegbe Salvation Bus-Stop ni Opebi to wa nilu eko, ni dede ago mejila osan. Agbenuso fun Ajo to n risi isele pajawiri nipinle eko, ogbeni Nosa Okunbor lo fidi isele naa mule fawon oniroyin. Ko sai fikun […]Continue Reading