Àwọn olórí ìjọ ọmọlẹ́yìn Krítì nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ ti tẹnumọ́ ìdì tó fi sepàtàkì fáwọn ọmọlẹ́yìn Krítì láti máà kawọ́ gbera nídi ọ̀rọ̀ òsèlú, kíwọ́n sì ridájú pé àwọn kópa tó jọjú nídi ọ̀rọ̀ òsèlú.

Níbi ìpàdé kan tó wáyé nílu ìbàdàn niwọ́n ti sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ olùdánilẹ́kọ́ọ̀ níbi ètò náà, tí tún solùdarí ẹgbẹ́ tó n jà fẹ́tọ ọmọnìyàn, àtètò ìdánilẹ́kọ́ọ̀ nípa isẹ́ láwùjọ, ọ̀gbẹ́ni Nimi Walson-Jack tó sọ̀rọ̀ lórí àkòrí, tóníse pẹ̀lú ẹ̀kọ́ nípa ọ̀rọ̀ òsèlú, lòun gbàgbọ́ pé, ètò ìjọba àwarawa nílò kíkópa tó jọjú gbogbo èèyàn láifi tẹ̀sìn tàbí èyíkèyí ẹ̀yà se.

Ó wá gbàwọn ọmọ lẹ́yìn krístì náà níyànjú láti máà se rí ọ̀rọ̀ òsèlú bí ìgbésẹ̀ kòkànmí, bíkòse pé, kíwọ́n ri gẹ́gẹ́ bí ànfàní láti ní àyípadà ọkàn.

Núní ọ̀rs tìẹ, òjísẹ́ Ọlọ̀run Fẹmi Emmanuẹl náà gbàwọn ìjọ nímọ̀ràn láti lọ darapọ̀ máwọn ẹgbẹ́ òsèlú tó báwùwọ́n lágbègbè kóòwá wọn, pẹ̀lú èróngbà jíjáwé olúborí nínú àwọn ètò ìdìbò tóbá ńwáyé,  sáajú lalága ìpàdé náà, PFN, nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ Ẹniọwọ Samson Ajetomọbi sọ pé, pàtàkì ìpàdé náà ni láti jẹ́ káwọn èèyàn lanyipa ọkàn nípa ọ̀rọ̀ òsèlú láwọn ilé ìjọsì.

Wojuade               

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *