Yoruba

Ijoba Apapo Dewo Lori Ofin Isede Farun Covid-19

Ijoba Apapo Orileede ti sun isede to waye lori arun Covid-19, alaago mewa ale si ago mejila oru titi di ago merin idaji, gege bi ara igbese didena itankale arun covid-19.

Alaga Igbimo amuseya tileese Aare gbekale lori arun covid-19, Ogbeni Boss Mustapha, lo siso loju oro yii nibi ipade kan to waye nilu Abuja, pelu alaye pe, awon eeyan tise won je ko se maa se inkan, niwon fun lanfani ati rin loru papa julo awon arinrin ajo tiwon sese nde latoke okun.

Ogbeni Mustapha ko sai tun so di mimo pe gbogbo awon ofin ati liana ti won ti de  irin ajo onile ati lawon Oja yika orileede yii ni joba ti ka se kuro lori re.

Niba yina, Ogbeni Mustapha wa ro awon ipinle to n gbero lati si awon ile iwe pada, kiwon ridaju pe, awon se amuse gbogbo awon ofin atilana toromo didena arun covid – 19, faabo awon omo naa.

Folakemi Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *