News Yoruba

Àjọ INEC sàgbékalẹ̀ ojú-òpó ìgbàlódé fésì àtúndì ìbò nípinlẹ̀ Imo

Àjọ elétò ìdìbò INEC, sọpó òhun ti ságbékalẹ̀ ojú-òpó ìgbìlódé tí wọn yóò ti máà kóò èsì ìbò jọ́ọ̀ fétò ìdìbò ẹkùn ìlàa-óòdúrún Imo, èyí tí yóò wáyé lọ́jọ́ kọkanlegbọn.

Alákoso àjọ INEC, nípinlẹ̀ náà, ọ̀jọ̀gbọ́n Francis Ezeonu sọ èyí fáwọn oníròyìn.

Nígbà tó ńsọ ìgbáradì àjọ INEC, fétò ìdìbò ìpínlẹ̀ náà, ọ̀jọ̀gbọ́n Ezeonu, sọpé àjọ se dáàdáà síì lásíkò ètò ìdìbò ọdún 2019, pẹ̀lú àlàyé àjọ náà yóò tún se jubẹlọ nínú àtúndì ìbò tófẹ́ wáyé ọ̀hún.

Ó fikun pé, pàtàkì àgbékalẹ̀ ojú-òpó ìgbàlódé ọ̀hún níì láti fẹsẹ̀ àkóyawọ́ àti gbangbalàsá múlẹ̀ nínú ètò ìdìbò.

idogbe   

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *