News Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti késí ẹ̀ka àjọètò-ìlera, Johẹsu láti sẹ̀wẹ̀lé ìyansẹ́lódì tíwọ́n gùnlé jákè-jádò ilẹ̀ yíì.

Alákoko fétò ìlera, Díkítà Osagie Ehanire, ẹnito sọ̀rọ̀ yíì níbi àbò ikọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid-19, nílu Abuja rọ àwọn òsìsẹ́ ọhun láti sọ àsọyépọ̀ pẹ̀lú àwọn tọ́rọkàn.

Alákoko sọ̀rọ̀ yíì wákàtí diẹ lẹ́yìn táàrẹ, àjọ Johesu, Dókítà Biobelomoye Josiah, rọ ìjọba àpapọ̀ láti dáhùn àwọn ìbere wọn, bótotọ́ àti bótiyẹ.

Ilésẹ́ tó ńrísí isẹ́ sọpé, ìyansẹ́lódì ọ̀hún kóò bófimu, tó sì Johesu láti sẹ́wẹ́lé ìyansẹ́lódì kòsì sọ̀rọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn tóòye.

idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *