News Yoruba

Gomina Seyi Makinde Dupe Fun Isokan Ileyi Leyin Ogota Odun.

Bi ile yi se nsayeye ogota odun ti o gba ominira, Gomina Seyi Makinde ti Ipinle Oyo fe ki awon omo ile yi dupe lowo Olorun fun isokan ile yi fun ogota odun laifi oniruru ipenija se.

O soro yi lasiko akanse isin lati sami ayeye ogota odun ominira ile yi to waye ni St. Peters Cathedral, Aremo, Ibadan.

Gomina Makinde eniti akowe ijoba ipinle Oyo, Arabinrin Olubamiwo Adeosu soju fun ni o se Pataki ati fope fun olorin nitori isokan to w anile yi.

Nine iwasu ti akori re je “E je ki idajo ododo joba”, Alufa agba St. Peter’s Cathedral, Aremo Ibadan, Eni Owo, Adebiyi Adewale ni ko si ohun ti o lee mu alaafia joba bikode idajo ododo.

Eni Owo Adebiyi wa kesi awon omo ile I lati maa tesiwaju lati maa gbadura fun ilosiwaju ile yi.

Adebisi/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *